Ife Anthem

This time is now

 1. Ilé-ifèniorí’runayé
  ÌlúOòduà baba Yorùbá
  Èdùmàrètódáwasí’fè
  Kómáseba ’fejémówal’órí
  K’Olúwakómaarànwá se.Refrain
  IfèOòyè, E jígìrì
  E jígìrì, k’egbéIfèga
  Olórí aye ni’fèOòyè
  K’ámúralátitès’íwájú
  ÒràmfèOn’íléiná
  Oòduà a wèririjagun
  Òkànlén’írúnirúnmolè
  E gbé ’fèlé’kĕ ’sòrogbogbo
 2. Ilé-ifèb’ojúmótimówá
  Ìlúàsà on ìlúèsìn
  GbogboYorùbá e káre ’fè
  Ká lo w’ohunàdáyébát’ójo’jú
  IléOòduàIfèl’ówà
  OpáÒràn’yàn; Ilé-Ifèni.
  ’ BojiMorèmiIlé-Ifèni
  Ará, e káre ’fèOòdáyé.Refrain
  IfèOòyè, E jígìrì
  E jígìrì, k’egbéIfèga
  Olórí aye ni’fèOòyè
  K’ámúralátitès’íwájú
  ÒràmfèOn’íléiná
  Oòduà a wèririjagun
  Òkànlén’írúnirúnmolè
  E gbé ’fèlé’kĕ ’sòrogbogboAase!

ILE-IFE, where the world begins , the cradle and source of yoruba and NATURAL capital of the black race.